-
Jóṣúà 10:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Nígbà tí wọ́n mú àwọn ọba yìí dé ọ̀dọ̀ Jóṣúà, ó pe gbogbo ọkùnrin Ísírẹ́lì, ó sì sọ fún àwọn ọ̀gágun nínú àwọn ọkùnrin ogun tó bá a lọ pé: “Ẹ bọ́ síwájú. Ẹ gbé ẹsẹ̀ yín lé ẹ̀yìn ọrùn àwọn ọba yìí.” Wọ́n wá bọ́ síwájú, wọ́n sì gbé ẹsẹ̀ wọn lé ẹ̀yìn ọrùn wọn.+
-