Àìsáyà 30:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ẹ ó sọ fàdákà tí ẹ fi bo àwọn ère gbígbẹ́ yín àti wúrà tí ẹ fi bo àwọn ère onírin*+ yín di aláìmọ́. Ẹ ó sọ wọ́n nù bí aṣọ tí wọ́n fi ṣe nǹkan oṣù, ẹ ó sì sọ fún wọn pé: “A ò fẹ́ mọ́!”*+
22 Ẹ ó sọ fàdákà tí ẹ fi bo àwọn ère gbígbẹ́ yín àti wúrà tí ẹ fi bo àwọn ère onírin*+ yín di aláìmọ́. Ẹ ó sọ wọ́n nù bí aṣọ tí wọ́n fi ṣe nǹkan oṣù, ẹ ó sì sọ fún wọn pé: “A ò fẹ́ mọ́!”*+