Diutarónómì 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 o ò gbọ́dọ̀ fetí sí ọ̀rọ̀ wòlíì yẹn tàbí ti alálàá yẹn,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ń dán yín wò+ kó lè mọ̀ bóyá ẹ fi gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara* yín nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run yín.+ Òwe 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+
3 o ò gbọ́dọ̀ fetí sí ọ̀rọ̀ wòlíì yẹn tàbí ti alálàá yẹn,+ torí Jèhófà Ọlọ́run yín ń dán yín wò+ kó lè mọ̀ bóyá ẹ fi gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara* yín nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run yín.+
3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+