Sáàmù 26:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Yẹ̀ mí wò, Jèhófà, kí o sì dán mi wò;Yọ́ èrò inú mi* àti ọkàn mi mọ́.+ Òwe 21:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gbogbo ọ̀nà èèyàn máa ń tọ́ lójú ara rẹ̀,+Àmọ́ Jèhófà máa ń ṣàyẹ̀wò ọkàn.*+ Òwe 24:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Tí o bá sọ pé: “Ṣebí a ò mọ̀ nípa rẹ̀,”Ṣé Ẹni tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn* kò mọ̀ ni?+ Bẹ́ẹ̀ ni, Ẹni tó ń wò ọ́* máa mọ̀Yóò sì san ẹnì kọ̀ọ̀kan lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.+
12 Tí o bá sọ pé: “Ṣebí a ò mọ̀ nípa rẹ̀,”Ṣé Ẹni tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn* kò mọ̀ ni?+ Bẹ́ẹ̀ ni, Ẹni tó ń wò ọ́* máa mọ̀Yóò sì san ẹnì kọ̀ọ̀kan lẹ́san gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ rẹ̀.+