Diutarónómì 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá lé wọn kúrò níwájú rẹ, má sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Òdodo mi ló mú kí Jèhófà mú mi wá gba ilẹ̀ yìí.’+ Torí ìwà burúkú àwọn orílẹ̀-èdè yìí+ ni Jèhófà ṣe máa lé wọn kúrò níwájú rẹ. Diutarónómì 32:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.
4 “Tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ bá lé wọn kúrò níwájú rẹ, má sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Òdodo mi ló mú kí Jèhófà mú mi wá gba ilẹ̀ yìí.’+ Torí ìwà burúkú àwọn orílẹ̀-èdè yìí+ ni Jèhófà ṣe máa lé wọn kúrò níwájú rẹ.
15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.