Diutarónómì 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí iná tó ń jóni run ni Jèhófà Ọlọ́run yín,+ Ọlọ́run tó fẹ́ kí ẹ máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo.+ Hébérù 12:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí Ọlọ́run wa jẹ́ iná tó ń jóni run.+