-
Ẹ́kísódù 24:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wá bá mi lórí òkè, kí o sì dúró síbẹ̀. Màá fún ọ ní àwọn wàláà òkúta tí èmi yóò kọ òfin àti àṣẹ sí láti fún àwọn èèyàn náà ní ìtọ́ni.”+
-
-
Ẹ́kísódù 32:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Iṣẹ́ ọnà Ọlọ́run ni àwọn wàláà náà, Ọlọ́run ló sì kọ ọ̀rọ̀ sára rẹ̀.+
-