-
Ẹ́kísódù 32:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ni Áárónì bá sọ fún wọn pé: “Ẹ gba yẹtí wúrà+ tó wà ní etí àwọn ìyàwó yín, àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin, kí ẹ sì kó o wá fún mi.”
-
-
Ẹ́kísódù 32:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Mósè bi Áárónì pé: “Kí ni àwọn èèyàn yìí ṣe sí ọ tí o fi mú kí wọ́n dá ẹ̀ṣẹ̀ ńlá?”
-