ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 1:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Àmọ́ pẹ̀lú gbogbo èyí, ẹ ò gba Jèhófà Ọlọ́run yín gbọ́,+

  • Sáàmù 106:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Síbẹ̀, wọn ò ka ilẹ̀ dáradára náà sí;+

      Wọn ò nígbàgbọ́ nínú ìlérí rẹ̀.+

      25 Ṣe ni wọ́n ń ráhùn nínú àgọ́ wọn;+

      Wọn ò fetí sí ohùn Jèhófà.+

  • Hébérù 3:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Torí náà, a rí i pé àìnígbàgbọ́ ò jẹ́ kí wọ́n lè wọnú rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́