Ẹ́kísódù 32:31, 32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Mósè wá pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ó sì sọ pé: “Ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn èèyàn yìí dá mà burú o! Wọ́n fi wúrà ṣe ọlọ́run fún ara wọn!+ 32 Àmọ́, tí o bá fẹ́, dárí jì wọ́n;+ bí bẹ́ẹ̀ kọ́, jọ̀ọ́, pa mí rẹ́ kúrò nínú ìwé rẹ tí o kọ.”+
31 Mósè wá pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà, ó sì sọ pé: “Ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn èèyàn yìí dá mà burú o! Wọ́n fi wúrà ṣe ọlọ́run fún ara wọn!+ 32 Àmọ́, tí o bá fẹ́, dárí jì wọ́n;+ bí bẹ́ẹ̀ kọ́, jọ̀ọ́, pa mí rẹ́ kúrò nínú ìwé rẹ tí o kọ.”+