ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 6:23-27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Bí ẹ ó ṣe máa súre+ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyí. Kí ẹ sọ fún wọn pé:

      24 “Kí Jèhófà bù kún ọ,+ kó sì pa ọ́ mọ́.

      25 Kí Jèhófà mú kí ojú rẹ̀ tàn sí ọ+ lára, kó sì ṣojúure sí ọ.

      26 Kí Jèhófà bojú wò ọ́, kó sì fún ọ ní àlàáfíà.”’+

      27 Kí wọ́n sì fi orúkọ mi sára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ kí n lè bù kún wọn.”+

  • Diutarónómì 21:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 “Kí àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì sì wá, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ti yàn wọ́n pé kí wọ́n máa ṣe ìránṣẹ́ fún òun,+ kí wọ́n sì máa súre ní orúkọ Jèhófà.+ Wọ́n á sọ bí wọ́n á ṣe máa yanjú gbogbo ọ̀rọ̀ tó bá jẹ mọ́ ìwà ipá.+

  • 2 Kíróníkà 30:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Níkẹyìn, àwọn ọmọ Léfì tó jẹ́ àlùfáà dìde dúró, wọ́n sì súre fún àwọn èèyàn náà;+ Ọlọ́run gbọ́ ohùn wọn, àdúrà wọn sì dé ibi mímọ́ tó ń gbé ní ọ̀run.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́