23 “Sọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Bí ẹ ó ṣe máa súre+ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyí. Kí ẹ sọ fún wọn pé:
24 “Kí Jèhófà bù kún ọ,+ kó sì pa ọ́ mọ́.
25 Kí Jèhófà mú kí ojú rẹ̀ tàn sí ọ+ lára, kó sì ṣojúure sí ọ.
26 Kí Jèhófà bojú wò ọ́, kó sì fún ọ ní àlàáfíà.”’+