Ẹ́kísódù 32:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jèhófà wá bẹ̀rẹ̀ sí í pèrò dà* lórí àjálù tó sọ pé òun máa mú bá àwọn èèyàn òun.+