Ẹ́kísódù 22:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ àjèjì tàbí kí ẹ ni ín lára,+ torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Léfítíkù 19:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Kí ẹ máa ṣe àjèjì tó ń bá yín gbé bí ọmọ ìbílẹ̀;+ kí ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara yín, torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
34 Kí ẹ máa ṣe àjèjì tó ń bá yín gbé bí ọmọ ìbílẹ̀;+ kí ẹ nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ bí ara yín, torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.