Léfítíkù 25:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 “‘Tí arákùnrin rẹ tó wà nítòsí bá di aláìní, tí kò sì lè bójú tó ara rẹ̀, kí o ràn án lọ́wọ́+ bí o ṣe máa ṣe fún àjèjì àti àlejò,+ kó lè máa wà láàyè pẹ̀lú rẹ.
35 “‘Tí arákùnrin rẹ tó wà nítòsí bá di aláìní, tí kò sì lè bójú tó ara rẹ̀, kí o ràn án lọ́wọ́+ bí o ṣe máa ṣe fún àjèjì àti àlejò,+ kó lè máa wà láàyè pẹ̀lú rẹ.