Nọ́ńbà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kórà+ ọmọ Ísárì,+ ọmọ Kóhátì,+ ọmọ Léfì+ wá gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú Dátánì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù+ pẹ̀lú Ónì ọmọ Péléétì, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.+ Nọ́ńbà 16:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ilẹ̀ sì lanu,* ó gbé wọn mì pẹ̀lú agbo ilé wọn àti gbogbo àwọn èèyàn Kórà+ pẹ̀lú gbogbo ẹrù wọn.
16 Kórà+ ọmọ Ísárì,+ ọmọ Kóhátì,+ ọmọ Léfì+ wá gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú Dátánì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù+ pẹ̀lú Ónì ọmọ Péléétì, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì.+