Jóṣúà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ẹ lọ káàkiri ibùdó, kí ẹ sì pa àṣẹ yìí fún àwọn èèyàn náà pé, ‘Ẹ ṣètò oúnjẹ sílẹ̀, torí ní ọjọ́ mẹ́ta òní, ẹ máa sọdá Jọ́dánì láti lọ gba ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín pé kó di tiyín.’”+
11 “Ẹ lọ káàkiri ibùdó, kí ẹ sì pa àṣẹ yìí fún àwọn èèyàn náà pé, ‘Ẹ ṣètò oúnjẹ sílẹ̀, torí ní ọjọ́ mẹ́ta òní, ẹ máa sọdá Jọ́dánì láti lọ gba ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín pé kó di tiyín.’”+