Diutarónómì 14:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “O gbọ́dọ̀ rí i pé ò ń san ìdá mẹ́wàá gbogbo ohun tí irúgbìn rẹ bá ń mú jáde lọ́dọọdún.+