1 Àwọn Ọba 8:56 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 56 “Ìyìn ni fún Jèhófà, tí ó fún àwọn èèyàn rẹ̀ Ísírẹ́lì ní ibi ìsinmi bí ó ti ṣèlérí.+ Kò sí ìkankan nínú gbogbo ìlérí tí ó ṣe nípasẹ̀ Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀ tí ó lọ láìṣẹ.+ 1 Kíróníkà 23:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Nítorí Dáfídì sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ti fún àwọn èèyàn rẹ̀ ní ìsinmi,+ yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù títí láé.+
56 “Ìyìn ni fún Jèhófà, tí ó fún àwọn èèyàn rẹ̀ Ísírẹ́lì ní ibi ìsinmi bí ó ti ṣèlérí.+ Kò sí ìkankan nínú gbogbo ìlérí tí ó ṣe nípasẹ̀ Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀ tí ó lọ láìṣẹ.+
25 Nítorí Dáfídì sọ pé: “Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ti fún àwọn èèyàn rẹ̀ ní ìsinmi,+ yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù títí láé.+