-
Diutarónómì 10:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà wá sọ fún mi pé, ‘Máa lọ níwájú àwọn èèyàn náà, kí ẹ múra láti gbéra, kí wọ́n lè lọ gba ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.’+
-