Diutarónómì 12:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Tí ibi tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ yàn láti fi orúkọ rẹ̀ sí+ bá jìnnà sí ọ, kí o pa lára ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran rẹ tí Jèhófà fún ọ, bí mo ṣe pa á láṣẹ fún ọ, kí o sì jẹ ẹ́ nínú àwọn ìlú* rẹ nígbàkigbà tó bá wù ọ́.*
21 Tí ibi tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ yàn láti fi orúkọ rẹ̀ sí+ bá jìnnà sí ọ, kí o pa lára ọ̀wọ́ ẹran tàbí agbo ẹran rẹ tí Jèhófà fún ọ, bí mo ṣe pa á láṣẹ fún ọ, kí o sì jẹ ẹ́ nínú àwọn ìlú* rẹ nígbàkigbà tó bá wù ọ́.*