Léfítíkù 4:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Kó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé orí ẹran ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, kó sì pa á ní ibì kan náà tó ti pa ẹran ẹbọ sísun.+ 30 Kí àlùfáà fi ìka rẹ̀ mú lára ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, kó fi sára àwọn ìwo pẹpẹ ẹbọ sísun, kó sì da gbogbo ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ.+
29 Kó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé orí ẹran ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, kó sì pa á ní ibì kan náà tó ti pa ẹran ẹbọ sísun.+ 30 Kí àlùfáà fi ìka rẹ̀ mú lára ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, kó fi sára àwọn ìwo pẹpẹ ẹbọ sísun, kó sì da gbogbo ẹ̀jẹ̀ tó kù sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ.+