- 
	                        
            
            Diutarónómì 17:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        2 “Ká sọ pé ọkùnrin tàbí obìnrin kan wà láàárín rẹ, nínú èyíkéyìí lára àwọn ìlú rẹ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ, tó ń ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ, tó sì ń tẹ májẹ̀mú rẹ̀ lójú,+ 3 tó wá yà bàrá, tó sì lọ ń jọ́sìn àwọn ọlọ́run míì, tó ń forí balẹ̀ fún wọn tàbí tó ń forí balẹ̀ fún oòrùn tàbí òṣùpá tàbí gbogbo ọmọ ogun ọ̀run,+ ohun tí mi ò pa láṣẹ.+ 
 
-