ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 11:13-20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “‘Àwọn ẹ̀dá tó ń fò tí ẹ máa kà sí ohun ìríra nìyí; ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ wọ́n, torí ohun ìríra ni wọ́n jẹ́: ẹyẹ idì,+ idì ajẹja, igún dúdú,+ 14 àwòdì pupa àti gbogbo onírúurú àwòdì dúdú, 15 gbogbo onírúurú ẹyẹ ìwò, 16 ògòǹgò, òwìwí, ẹyẹ àkẹ̀ àti gbogbo onírúurú àṣáǹwéwé, 17 òwìwí kékeré, ẹyẹ àgò, òwìwí elétí gígùn, 18 ògbùgbú, ẹyẹ òfú, igún, 19 ẹyẹ àkọ̀, gbogbo onírúurú ẹyẹ wádòwádò, àgbìgbò àti àdán. 20 Kí gbogbo ẹ̀dá abìyẹ́ tó ń gbá yìn-ìn,* tí wọ́n ń fi ẹsẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rìn jẹ́ ohun ìríra fún yín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́