-
Diutarónómì 28:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Orí ni Jèhófà máa fi ọ́ ṣe, kò ní fi ọ́ ṣe ìrù; òkè+ lo máa wà, o ò ní sí nísàlẹ̀, tí o bá ń ṣègbọràn sí àwọn àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ tí mò ń pa fún ọ lónìí pé kí o máa pa mọ́ kí o sì máa tẹ̀ lé.
-
-
1 Àwọn Ọba 4:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ó ń bójú tó gbogbo ohun tó wà lápá Odò+ níbí,* láti Tífísà dé Gásà,+ títí kan gbogbo àwọn ọba tó wà lápá Odò níbí; ó sì ní àlàáfíà ní gbogbo agbègbè tó yí i ká.+ 25 Júdà àti Ísírẹ́lì ń gbé lábẹ́ ààbò ní gbogbo ọjọ́ ayé Sólómọ́nì, kálukú lábẹ́ àjàrà rẹ̀ àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀, láti Dánì títí dé Bíá-ṣébà.
-