Diutarónómì 12:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Àmọ́ ìgbàkígbà tó bá wù yín* lẹ lè pa ẹran kí ẹ sì jẹ ẹ́,+ bí Jèhófà Ọlọ́run yín bá ṣe bù kún yín tó ní gbogbo ìlú* yín. Ẹni tó jẹ́ aláìmọ́ àti ẹni tó mọ́ lè jẹ ẹ́, bí ẹ ṣe máa ń jẹ egbin tàbí àgbọ̀nrín. Diutarónómì 14:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn ẹran tí ẹ lè jẹ nìyí:+ akọ màlúù, àgùntàn, ewúrẹ́, 5 àgbọ̀nrín, egbin, èsúwó, ẹ̀kìrì,* ẹtu, àgùntàn igbó àti àgùntàn orí àpáta.
15 “Àmọ́ ìgbàkígbà tó bá wù yín* lẹ lè pa ẹran kí ẹ sì jẹ ẹ́,+ bí Jèhófà Ọlọ́run yín bá ṣe bù kún yín tó ní gbogbo ìlú* yín. Ẹni tó jẹ́ aláìmọ́ àti ẹni tó mọ́ lè jẹ ẹ́, bí ẹ ṣe máa ń jẹ egbin tàbí àgbọ̀nrín.
4 Àwọn ẹran tí ẹ lè jẹ nìyí:+ akọ màlúù, àgùntàn, ewúrẹ́, 5 àgbọ̀nrín, egbin, èsúwó, ẹ̀kìrì,* ẹtu, àgùntàn igbó àti àgùntàn orí àpáta.