ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Kí ara àgùntàn yín dá ṣáṣá,+ kó jẹ́ akọ, ọlọ́dún kan. Ẹ lè mú lára àwọn ọmọ àgbò tàbí àwọn ewúrẹ́. 6 Kí ẹ máa tọ́jú rẹ̀ títí di ọjọ́ kẹrìnlá oṣù yìí,+ kí gbogbo àpéjọ* àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì pa á ní ìrọ̀lẹ́.*+

  • 2 Kíróníkà 35:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Jòsáyà fún àwọn èèyàn náà ní agbo ẹran, akọ ọ̀dọ́ àgùntàn àti akọ ọmọ ewúrẹ́, láti fi ṣe ẹran Ìrékọjá fún gbogbo àwọn tó wá, àpapọ̀ rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000), ó tún fi ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) màlúù kún un. Inú ohun ìní ọba ni àwọn nǹkan yìí ti wá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́