-
Diutarónómì 12:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Kàkà bẹ́ẹ̀, ibikíbi tí Jèhófà Ọlọ́run yín bá yàn pé kí orúkọ rẹ̀ wà àti ibi tó bá ń gbé láàárín gbogbo ẹ̀yà yín ni kí ẹ ti máa wá a, ibẹ̀ sì ni kí ẹ máa lọ.+
-
-
1 Àwọn Ọba 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ní àkókò yẹn, àwọn aṣẹ́wó méjì wá sọ́dọ̀ ọba, wọ́n sì dúró níwájú rẹ̀.
-
-
Sáàmù 122:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ní báyìí, ẹsẹ̀ wa dúró
Ní àwọn ẹnubodè rẹ, ìwọ Jerúsálẹ́mù.+
-