Diutarónómì 5:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Kí ẹ rí i pé ohun tí Jèhófà Ọlọ́run yín pa láṣẹ fún yín gẹ́lẹ́ lẹ̀ ń ṣe.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ yà sí ọ̀tún tàbí sí òsì.+ Diutarónómì 12:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Gbogbo ọ̀rọ̀ tí mò ń pa láṣẹ fún yín ni kí ẹ rí i pé ẹ tẹ̀ lé.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi kún un, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ yọ kúrò nínú rẹ̀.+
32 Kí ẹ rí i pé ohun tí Jèhófà Ọlọ́run yín pa láṣẹ fún yín gẹ́lẹ́ lẹ̀ ń ṣe.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ yà sí ọ̀tún tàbí sí òsì.+
32 Gbogbo ọ̀rọ̀ tí mò ń pa láṣẹ fún yín ni kí ẹ rí i pé ẹ tẹ̀ lé.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ fi kún un, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ yọ kúrò nínú rẹ̀.+