-
Ẹ́kísódù 21:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 “Tí ẹnì kan bá lu èèyàn pa, kí ẹ pa onítọ̀hún.+
-
-
Nọ́ńbà 35:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “‘Àmọ́ tó bá jẹ́ ohun tí wọ́n fi irin ṣe ni ẹnì kan fi lu ẹnì kejì rẹ̀, tó sì kú, apààyàn ni. Ẹ gbọ́dọ̀ pa apààyàn náà.+
-
-
Diutarónómì 27:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá lúgọ de ọmọnìkejì rẹ̀, tó sì pa á.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
-