Diutarónómì 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀, ṣe ni kí o mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀ kúrò ní Ísírẹ́lì,+ kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ.
13 O* ò gbọ́dọ̀ káàánú rẹ̀, ṣe ni kí o mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀ kúrò ní Ísírẹ́lì,+ kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ.