33 “‘Ẹ má sọ ilẹ̀ tí ẹ̀ ń gbé di ẹlẹ́gbin, torí ẹ̀jẹ̀ máa ń sọ ilẹ̀+ di ẹlẹ́gbin, kò sì sí ètùtù fún ẹ̀jẹ̀ tí ẹnì kan ta sórí ilẹ̀ àyàfi ẹ̀jẹ̀ ẹni náà tó ta á sílẹ̀.+
21Ìyàn+ kan mú nígbà ayé Dáfídì, ọdún mẹ́ta tẹ̀ léra ló sì fi mú. Nítorí náà Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà, Jèhófà sì sọ pé: “Ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ wà lórí Sọ́ọ̀lù àti lórí ilé rẹ̀, nítorí ó pa àwọn ará Gíbíónì.”+