Diutarónómì 24:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Tí ọkùnrin kan bá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbéyàwó, kò gbọ́dọ̀ dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun, wọn ò sì gbọ́dọ̀ yan àwọn iṣẹ́ míì fún un. Kó wà lómìnira fún ọdún kan, kó sì dúró sílé kó lè máa múnú ìyàwó rẹ̀ dùn.+
5 “Tí ọkùnrin kan bá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbéyàwó, kò gbọ́dọ̀ dara pọ̀ mọ́ àwọn ọmọ ogun, wọn ò sì gbọ́dọ̀ yan àwọn iṣẹ́ míì fún un. Kó wà lómìnira fún ọdún kan, kó sì dúró sílé kó lè máa múnú ìyàwó rẹ̀ dùn.+