-
Diutarónómì 20:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ta ló sì ti ń fẹ́ obìnrin kan sọ́nà, àmọ́ tí kò tíì gbé e níyàwó? Kó gbéra, kó sì pa dà sí ilé rẹ̀.+ Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ó lè kú sójú ogun, ọkùnrin míì á sì fi obìnrin náà ṣaya.’
-
-
Òwe 5:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Kí orísun omi* rẹ ní ìbùkún,
Kí o sì máa yọ̀ pẹ̀lú aya ìgbà èwe rẹ,+
-