ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 13:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 A rí àwọn Néfílímù níbẹ̀, àwọn ọmọ Ánákì,+ tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ* àwọn Néfílímù. Lójú wọn, ṣe la dà bíi tata, bẹ́ẹ̀ náà ló sì rí lójú tiwa.”

  • Nọ́ńbà 14:1-3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Gbogbo àpéjọ náà ń kígbe, àwọn èèyàn náà ń ké, wọ́n sì ń sunkún ní gbogbo òru+ yẹn. 2 Gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá bẹ̀rẹ̀ sí í kùn sí Mósè àti Áárónì,+ gbogbo àpéjọ náà sì ń sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí wọn pé: “Ó sàn ká ti kú sí ilẹ̀ Íjíbítì tàbí ká tiẹ̀ ti kú sínú aginjù yìí! 3 Kí ló dé tí Jèhófà fẹ́ mú wa wá sí ilẹ̀ yìí kí wọ́n lè fi idà+ pa wá? Wọ́n á kó+ àwọn ìyàwó wa àti àwọn ọmọ wa lẹ́rú. Ǹjẹ́ kò ní dáa ká pa dà sí Íjíbítì?”+

  • Nọ́ńbà 32:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nígbà tí wọ́n gòkè lọ sí Àfonífojì Éṣíkólì,+ tí wọ́n sì rí ilẹ̀ náà, wọ́n kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n má bàa lọ sí ilẹ̀ tí Jèhófà fẹ́ fún wọn.+

  • Diutarónómì 1:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Báwo ni ibi tí à ń lọ ṣe rí? Àwọn arákùnrin wa mú kí ẹ̀rù bà wá,*+ wọ́n sọ pé: “Àwọn èèyàn náà lágbára, wọ́n sì ga jù wá lọ, àwọn ìlú wọn tóbi, wọ́n sì mọ odi rẹ̀ kan ọ̀run,*+ a sì rí àwọn ọmọ Ánákímù+ níbẹ̀.”’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́