-
Léfítíkù 25:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Inú àwọn orílẹ̀-èdè tó yí yín ká ni kí ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin yín ti wá, ẹ lè ra ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin lọ́wọ́ wọn.
-
-
Léfítíkù 25:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Ẹ lè jẹ́ kí àwọn ọmọ yín jogún wọn kí wọ́n lè di ohun ìní wọn títí láé. Ẹ lè lò wọ́n bí òṣìṣẹ́, àmọ́ ẹ má fi ọwọ́ líle mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ arákùnrin yín.+
-
-
Jóṣúà 9:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Lẹ́yìn náà, Jóṣúà pè wọ́n, ó sì sọ fún wọn pé: “Kí ló dé tí ẹ tàn wá, tí ẹ sọ pé, ‘Ibi tó jìnnà gan-an sí yín la ti wá,’ nígbà tó jẹ́ pé àárín wa níbí lẹ̀ ń gbé?+
-