ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 9:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àwọn tó kọ́kọ́ pa dà sídìí ohun ìní wọn, ní àwọn ìlú wọn, ni àwọn kan lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì.*+

  • Ẹ́sírà 7:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Bákan náà, mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé, ẹ kò gbọ́dọ̀ gba owó orí, ìṣákọ́lẹ̀*+ tàbí owó ibodè lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni tó jẹ́ àlùfáà, ọmọ Léfì, olórin,+ aṣọ́nà, ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tàbí òṣìṣẹ́ nínú ilé Ọlọ́run yìí.

  • Ẹ́sírà 8:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Mo wá pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n lọ bá Ídò tó jẹ́ olórí ní ibi tí wọ́n ń pè ní Kásífíà. Mo ní kí wọ́n sọ fún Ídò àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* tí wọ́n wà ní Kásífíà pé kí wọ́n bá wa mú àwọn òjíṣẹ́ wá fún ilé Ọlọ́run wa.

  • Nehemáyà 3:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ tí wọ́n ń gbé ní Ófélì+ ṣe iṣẹ́ àtúnṣe títí dé iwájú Ẹnubodè Omi+ ní ìlà oòrùn àti ilé gogoro tó yọ jáde náà.

  • Nehemáyà 7:60
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 60 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ àti ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé àádọ́rùn-ún àti méjì (392).

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́