Ẹ́kísódù 22:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ àjèjì tàbí kí ẹ ni ín lára,+ torí àjèjì lẹ jẹ́ ní ilẹ̀ Íjíbítì.+