- 
	                        
            
            Ìṣe 7:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        34 Mo ti rí bí wọ́n ṣe ń fìyà jẹ àwọn èèyàn mi tó wà ní Íjíbítì, mo sì ti gbọ́ bí wọ́n ṣe ń kérora,+ mo ti sọ̀ kalẹ̀ wá láti gbà wọ́n sílẹ̀. Ní báyìí, wá, màá rán ọ lọ sí Íjíbítì.’ 
 
-