-
Jóṣúà 8:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Gbogbo Ísírẹ́lì, àwọn àgbààgbà wọn, àwọn olórí àtàwọn adájọ́ wọn dúró sí ẹ̀gbẹ́ méjèèjì Àpótí náà, níwájú àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì, tí wọ́n ń gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà. Àwọn àjèjì àtàwọn ọmọ ìbílẹ̀ náà wà níbẹ̀.+ Ìdajì wọn dúró síwájú Òkè Gérísímù, ìdajì tó kù sì wà níwàjú Òkè Ébálì+ (bí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà ṣe pa á láṣẹ tẹ́lẹ̀),+ láti súre fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì.
-