Léfítíkù 19:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣépè fún* adití tàbí kí ẹ fi ohun ìdènà síwájú afọ́jú,+ ẹ sì gbọ́dọ̀ máa bẹ̀rù Ọlọ́run yín.+ Èmi ni Jèhófà.
14 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣépè fún* adití tàbí kí ẹ fi ohun ìdènà síwájú afọ́jú,+ ẹ sì gbọ́dọ̀ máa bẹ̀rù Ọlọ́run yín.+ Èmi ni Jèhófà.