Léfítíkù 18:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó bàbá rẹ lò pọ̀.+ Ìyẹn máa dójú ti bàbá rẹ.* 1 Kọ́ríńtì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní tòótọ́, wọ́n ròyìn ìṣekúṣe*+ tó ṣẹlẹ̀ láàárín yín, irú ìṣekúṣe* bẹ́ẹ̀ kò tiẹ̀ sí láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, pé ọkùnrin kan ń fẹ́* ìyàwó bàbá rẹ̀.+
5 Ní tòótọ́, wọ́n ròyìn ìṣekúṣe*+ tó ṣẹlẹ̀ láàárín yín, irú ìṣekúṣe* bẹ́ẹ̀ kò tiẹ̀ sí láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, pé ọkùnrin kan ń fẹ́* ìyàwó bàbá rẹ̀.+