-
Léfítíkù 26:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Bí ẹ ṣe ń jẹ irè oko tó ṣẹ́ kù láti ọdún tó kọjá, ẹ máa ní láti palẹ̀ èyí tó ṣẹ́ kù mọ́ kí tuntun lè wọlé.