Nọ́ńbà 21:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ísírẹ́lì wá ní kí àwọn ìránṣẹ́ lọ bá Síhónì ọba àwọn Ámórì pé:+ 22 “Jẹ́ ká gba ilẹ̀ rẹ kọjá. A ò ní yà sínú oko tàbí sínú ọgbà àjàrà. A ò ní mu omi inú kànga kankan. Ojú Ọ̀nà Ọba la máa gbà títí a fi máa kọjá ní ilẹ̀+ rẹ.”
21 Ísírẹ́lì wá ní kí àwọn ìránṣẹ́ lọ bá Síhónì ọba àwọn Ámórì pé:+ 22 “Jẹ́ ká gba ilẹ̀ rẹ kọjá. A ò ní yà sínú oko tàbí sínú ọgbà àjàrà. A ò ní mu omi inú kànga kankan. Ojú Ọ̀nà Ọba la máa gbà títí a fi máa kọjá ní ilẹ̀+ rẹ.”