ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìdárò 2:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ojú mi ti di bàìbàì nítorí omijé.+

      Inú* mi ń dà rú.

      A ti tú ẹ̀dọ̀ mi jáde sí ilẹ̀, nítorí ìṣubú ọmọbìnrin* àwọn èèyàn mi,+

      Nítorí àwọn ọmọdé àti ọmọ jòjòló ń dá kú ní àwọn ojúde ìlú.+

  • Ìdárò 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Dìde! Bú sẹ́kún ní òru, ní ìbẹ̀rẹ̀ àkókò ìṣọ́.

      Tú ọkàn rẹ jáde bí omi níwájú Jèhófà.

      Gbé ọwọ́ rẹ sókè sí Ọlọ́run nítorí ẹ̀mí* àwọn ọmọ rẹ,

      Tó ń kú lọ nítorí ìyàn ní gbogbo oríta* ojú ọ̀nà.+

  • Ìdárò 4:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn obìnrin aláàánú ti fọwọ́ ara wọn se àwọn ọmọ wọn. +

      Wọ́n ti di oúnjẹ ọ̀fọ̀ fún wọn nígbà tí ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi wó lulẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́