Léfítíkù 26:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí náà, ṣe ni ẹ máa jẹ ẹran ara àwọn ọmọkùnrin yín, ẹ ó sì jẹ ẹran ara àwọn ọmọbìnrin yín.+ Ìdárò 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wò ó Jèhófà, wo ẹni tí o fìyà jẹ. Ṣé ó yẹ kí àwọn obìnrin máa jẹ ọmọ* tiwọn fúnra wọn, àwọn ọmọ tí wọ́n bí láìní àbùkù,+Àbí, ṣé ó yẹ kí wọ́n pa àwọn àlùfáà àti wòlíì nínú ibi mímọ́ Jèhófà?+ Ìdárò 4:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ajáko* pàápàá máa ń fún ọmọ wọn lọ́mú,Àmọ́ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi ti ya ìkà,+ bí àwọn ògòǹgò aginjù.+
20 Wò ó Jèhófà, wo ẹni tí o fìyà jẹ. Ṣé ó yẹ kí àwọn obìnrin máa jẹ ọmọ* tiwọn fúnra wọn, àwọn ọmọ tí wọ́n bí láìní àbùkù,+Àbí, ṣé ó yẹ kí wọ́n pa àwọn àlùfáà àti wòlíì nínú ibi mímọ́ Jèhófà?+
3 Àwọn ajáko* pàápàá máa ń fún ọmọ wọn lọ́mú,Àmọ́ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi ti ya ìkà,+ bí àwọn ògòǹgò aginjù.+