Òwe 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọlọ́rọ̀ ń ṣàkóso àwọn aláìní,Ẹni tó yá nǹkan sì ni ẹrú ẹni tó yá a ní nǹkan.+