Diutarónómì 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Aṣọ tí o wọ̀ ò gbó, ẹsẹ̀ rẹ ò sì wú jálẹ̀ ogójì (40) ọdún yìí.+ Nehemáyà 9:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ogójì (40) ọdún lo fi pèsè oúnjẹ fún wọn ní aginjù.+ Wọn ò ṣaláìní nǹkan kan. Aṣọ wọn ò gbó,+ ẹsẹ̀ wọn ò sì wú. Mátíù 6:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Torí náà, ẹ má ṣàníyàn láé,+ kí ẹ wá sọ pé, ‘Kí la máa jẹ?’ tàbí, ‘Kí la máa mu?’ tàbí, ‘Kí la máa wọ̀?’+
21 Ogójì (40) ọdún lo fi pèsè oúnjẹ fún wọn ní aginjù.+ Wọn ò ṣaláìní nǹkan kan. Aṣọ wọn ò gbó,+ ẹsẹ̀ wọn ò sì wú.
31 Torí náà, ẹ má ṣàníyàn láé,+ kí ẹ wá sọ pé, ‘Kí la máa jẹ?’ tàbí, ‘Kí la máa mu?’ tàbí, ‘Kí la máa wọ̀?’+