Diutarónómì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí o sì pàṣẹ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ààlà ilẹ̀ àwọn arákùnrin yín, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì,+ lẹ máa gbà kọjá, ẹ̀rù yín á sì máa bà wọ́n,+ torí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi.
4 Kí o sì pàṣẹ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ààlà ilẹ̀ àwọn arákùnrin yín, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì,+ lẹ máa gbà kọjá, ẹ̀rù yín á sì máa bà wọ́n,+ torí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi.