Ẹ́kísódù 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+ Ẹ́kísódù 23:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Màá mú kí àwọn èèyàn máa bẹ̀rù mi kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn,+ màá sì da àárín gbogbo àwọn tí ẹ bá pàdé rú. Màá mú kí ẹ ṣẹ́gun gbogbo ọ̀tá yín, wọ́n á sì sá lọ.*+
15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+
27 “Màá mú kí àwọn èèyàn máa bẹ̀rù mi kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn,+ màá sì da àárín gbogbo àwọn tí ẹ bá pàdé rú. Màá mú kí ẹ ṣẹ́gun gbogbo ọ̀tá yín, wọ́n á sì sá lọ.*+